Breaking News

OWOADE 1

ALL HAIL THE NEW ALAAFIN OBA AKEEM ABIMBOLA OWOADE, OWOADE 1

Oríkì Sango!A bí lumo bí òwúỌkọ̀ mi asọ̀ǹbọ̀-sọnbọ idàEbiti káwọ́ sẹ́yìn soro bíi agbọ́nẸ̀bìtì ká ọwọ́ ìjà léríÈyí tí yó ṣẹ ní àá ń wòyeSango!Sangiri làgiriÒ làgiri kàkà fìgbà ẹdùn bọ̀A wọ̀lú tìlù tariwoṢàngó oooooo Ka-bi-ye-si Alase! Ekeji orisa! Iku baba yeye, Alaafin oro mo jo gbo ti gbogbo Oyo mbo. Oranmiyan, Alaafin, oruntolu. Iba!…

Read more